ẸsinTrend
ẸsinTelly
Ẹ-Archive
Ẹ-Books
Ẹ-Jadwal
Ẹ-Channel
Ẹ-Search
Ẹ-Stories
ẸsinTVs
 
Close
ẸsinTelly
SetAdhan
Topics
Divans
Reciters
Writers
PrayTime
اغلق
 
 
                   
 

 

 
Ojule Koko Mewa Awon Akole Titun Fi Itan/Irohin/Ibeere Sowo Wadi Ni Ede Yoruba Agbo-Oro Yoruba Akopo
   
 
Tite Wole

  Create an account

Ojule Nyin Akoko

Tite Jade

 
 
Ifiseje Tire Awon Omo-Egbe Yoruba Se Ayewo Atoka Apoti Ifi Atoka Pamo Atokun Alantakun Awon Eda Ipamo
 
     
 

 

 
 
                  
 

Irohin Nitele-N-Tele

 
 

Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin
[ Alaiye Esin - Ibere Ati Idahun Imo Esin ]

·Nibo Ni Isokan Yoruba Yoo Ti Wa?
·TITUBA KURO NIBI ESE (AT-TAWBAH MIN AL-MA'ASIY)
·Kike Alkur'an Ati Awon Eko Re: Alaye Ola (Esan) kike AlKur'an Alaponle
·Kamalat, Omo Odun Mefa To Laisan Okan Ma N Pariwo, O Ni Kawon Omo Naijiria Ran
·IGBEYAWO NINU ISLAM: Itumo Igbeyawo; Kinni Erogba Igbeyawo Ninu Islam?
·Awon ipile meta Esin Islam ati awon Eri won Lati owo Shaikh Muhammad Ibn sulaima
·AKASO ODODO (Al- WASEELAH) - Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi -- Atunyewo
·Alaye lori Aayah (23) ninu Suuratu Furkooni
·Oorun didun igi ododo ti orewa nipa ajulo awon iya awon olugbagbo ododo
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
                  
 

Iwadi Ni Yoruba

 
 


 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
                  
 

Random Fatwas Updates

 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
                  
 

Ipase Awon Eto L'owoyi

 
 
Ko Si Oun Kankan Fun Nyin Nibi Yi Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo Mo Wa. Lati Ni Eto Si Awon Ohun Gbogbo Ti Ibiyi, E Gbodo Koko Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi Na Tabi Ki E Darapo Mo Wa.
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
                  
 

Tumo Yoruba Sede Miran

 
 
E Yan Ede Ti E Ba Fe Ni Sise Ipaaro Ede Kan Fun Ekeji:

 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
                  
 

Your Local Time

 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
                  
 

Awon Atoka Ti Atehinwa

 
 
Friday, April 29
· Esther Na Omo Oko Re Fo Loju, Lawon Olopaa Ba Wo o Dewaju Adajo
· Owo Te Daniel To N Lu Awon Eeyan Ni Jibiti Lori Facebook
· Charles Na Nani Daku N'Ilorin, O Ni o N Je Komo Oun Sunkun
· Mi o Sonu o, Iro Loko Mi n Pa Pe Oun Ko Ri Mi — Bukola
· Bilikis Sa Kuro Nileewe Nitori Tisa Fee Lu u, Ni Joe Atore e Ba Fipa Ba a Lo Po
· Kayeefi N'Ilorin: Baba Atawon Omo Meta Ku Sinu Ile, Won Ni Ege To Ni Majele
· Ile N Jeeyan, Awon Eni Nla Ti Re Koja Lo: Akintola n So Kiri Pe Awolowo Fee Fibo
· Owo Te Pasito Ati Sorosoro Ori Redio N'Ilorin, Ayederu Risiiti Ni Won Se
· Oro Oye Iyaloja N'Ijebu: Awon Ara Oja Kan Lawon Ko Fe Wuraola Kuforiji
· Abel Se 'Kinni' Fomo Odun Mesan-an L'Ondo, Ladajo Ba Ni Ko Loo Fe
· Afi Ki Buhari Gba Wa Lowo Awon Onise-ina Yii o
· Bee Gbogbo Wa Naa Lole N'ile Yii...
· Buhari, Die Die: Oun To Yeni L'oyeni...Beeni Alaseju Tite Ni i Te...
· Ijoba Soja... Ijoba Soja... Ijoba Soja: Owo Dowo Adebo, O n Ro Woo, Woo, Woo
· Odun Kejila Ree Ti Oko Mi Ti File Sile Fun Mi, Mi O Le Duro De e Mo — Rukayat
· Pasito Ni Olorun Fi Iran Han Oun Lati Koyawo Oun Sile, Niyen Ba Ni Iro Lo n Pa
· Aliu Je Kunbi Lowo, Lo Ba Tun Seku Pa a
· Nibo Ni Isokan Yoruba Yoo Ti Wa?
· Okunrin Mi-in N Se Kinni un Fun Iyawo Mi Ninu Ile Wa, Mi O Fe e Mo — Babatunde
· Obasanjo So Pe Koko Lara Oun Le o
· Olumide Lu Egbon Iyawo Re Ni Jibiti Milionu Mesan-an l'Agbado
· O Ma Se o, Omo Iya Meji Jona Mole n'Ilesa
· Nitori Indomie, Oluwaseun Gun Ore Re Pa l'Ondo
· Won Ji Aso Ati Owo Awon Omolooku n'Ilesa
· Ojo Ileya Ni Shehu Ati Hussein Pa Muhammadu, Ni Won Ba Ge Ori e Fi Soogun N'
· Nitori Oro Ti Ko To Nnkan, Ore Meji Figo Gun Ara Won Sakasaka L'Ekiti
· Ile N Jeeyan, Awon Eni Nla Ti Re Koja Lo: Oro Beyin Yo - Ladoke Akintola Gba Ise
· Iro Ni Adegboye N Pa, Won Ko Ni Ile Kankan L'Ajenisuwa — Baale Ajenisuwa
· Animasahun Niyawo Ti Mo Fe, Mi O Se Mo — Ayokunle
· Lori Bi Aare Muhammadu Buhari Ti Yan Awon Minisita Re Tuntun, Oun Taye N Wi Ree

Awon Atoka Ti O Ti Pe
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
                  
 

Onka Ni Oju-Agbo

 
 
Ni Wakati Yi, Awon Eniti Nwon Wa Ni Oju Agbo Lowo Yi Pelu Nyin Je 2 Ninu (Awon) Alejo Wa 3 Ninu (Awon) Olulo Wa Ati Omo-Egbe Awqaf, Awon Asiwaju Ninu Egbe Olomokunrin Fatih-ul-Fattah Ati Ninu Egbe Olomobirin Taqiah Sisters. Lati Ri Awon Ti Nwon Ti Fi Oruko Sile Bi Ti Nyin Ti Nwon Wa Ni Oju-Agbo Pelu Nyin Lowo Yi E Te Lati Ri Ni Ibiyi

E Koi Ti Fi Orkuo Sile Lati Wole Si Oju Agbo. Ti E Ba Fe Lati Lo Si Ibiyi E Le Fi Oruko Sile L'ofe Ni Ibiyi
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
Itan/Irohin/Ibere Nla L'oni

Ko Si Atoka / Itan Kankan Fun Nyin L'owo Yii Nitori Wipe E Koi Ti Fi Oruko Sile Lati Lo Si Ibiyi. Fun Gbogbo awon Anfaani Ti O Wa Fun Apere Awon Atoka / Itan Ti O N Lo L'owo Ati Awon Atoka Titun Ti Oojo, E Gbodo Fi Oruko Sile L'ofe Lati Lo Si Ibiyi Tabi Ki E Darapo L'ati Di Ara Wa.

 

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

E Woju Won o: Awon Ti Won Ko Owo Naijiria Je Ree o
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 7635 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

E Woju Won o: Awon Ti Won Ko Owo Naijiria Je Ree o

Nigba ti oro naa koko bere, ohun tawon eeyan ro ni pe ijoba Muhammadu Buhari n wa gbogbo ona lati mu awon ti won ba Aare ana, Goodluck Jonathan, sise ni. Sugbon nigba ti asiri nla naa bere si i tu sita, kaluku loro naa ya lenu. Nipari osu kejo, odun yii, ni ijoba Buhari gbe igbimo kan dide, igbimo oniwadii ni, ohun ti won si fe ki igbimo yii wadii ni bi awon ti won n seto aabo ile yii lati odun 2007 se na awon owo ti won ko fun won. Ohun to fa eyi ni pe laarin odun naa, ileese to n mojuto eka eto aabo fun ijoba apapo pese owo lati ri i pe won ra irinse to po, won ra eelo ogun jija, won ra ibon atawon eronpileeni repete, paapaa nitori ogun awon Boko Haram to gba gbogbo ilu kan. Sugbon bi won ti n gba owo to, bee lawon soja n pariwo pe awon ko nirinse, ti won si n sa loju ogun fun awon Boko Haram, oro naa si di nnkan abuku fun ijoba apapo, nigba tawon soja won ki ere mole ti won sa lo.

Bi e ko ba gbagbe, laye ijoba Jonathan, awon soja bii ogota kan wa ti won dajo iku fun, esun ti won fi kan won ni pe won sa loju ogun niwaju awon Boko Haram, won sa lo pata ti enikan ko ri won. Die lo ku ki won pa won, afi nigba ti Buhari gbajoba to da won sile. Esun ti won fi kan won ni pe won ko duro jagun, nigba ti won ti foju gan-an-ni awon omo Boko Haram yii, nise ni won ki ere mole ti won n sa lo. Sugbon awon soja ti won mu nigba naa soro, won ni ko si bi awon se le koju awon Boko Haram, nitori irinse ti won n lo lagbara, o si po ju tawon lo gan-an. Nidii eyi, won ni bi awon pe egberun ti awon dojuko awon omo Boko Haram ti ko ju mewaa lo, bii eni to mu adie ni won yoo mu awon, nitori awon irinse ti won n lo, irinse igbalode to lagbara ni, eni kookan won si le pa bii ogun eeyan laarin iseju meji pere. Nise lo da bii pe owo lasan lawon fi n ja ni tawon, eni ti ko ba nirinse ogun ko si le koju ogun.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 7635 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara

Odo Ni Wolii Moses Ti Ni Ki David Loo We Iwe Isegun, Lo Ba Fogbon Ji Moto Re Gbe
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 2484 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Kayode Omotosho, Ilorin

Odo Ni Wolii Moses Ti Ni Ki David Loo We Iwe Isegun, Lo Ba Fogbon Ji Moto Re Gbe N'Ilorin

Afi ki awon eeyan maa sora ni awujo wa bayii pelu bo se je pe orisiirisii awon wolii lo ti wa nita, to si je pe opo ninu won kan n je ipe ara won ni, ki i se ipe Olorun ni won n je. Abi kin ni ka ti pe ti Wolii Moses Adegbite ti owo ileese olopaa ipinle Kwara te pe o ji oko gbe sa lo nibi to ti n jise to ni Olorun ran oun.

Ojo Isegun, Tusde, ose to koja ni ileese olopaa ipinle Kwara taari alagba Moses, eni odun mejidinlogoji si kootu majisreeti to wa niluu Ilorin, niwaju Adajo F.O Olokoyo.

Nigba to n safihan afurasi odaran naa fun ile-ejo, olopaa to n soju ijoba, Inspekito Mojisola Olamokun, fesun kan Moses pe se lo lu jibiti oko, eyi to tako abala kan iwe ofin to de iwa odaran tipinle Kwara. O salaye pe ni nnkan bii aago marun-un aabo irole, ojo kejo, osu kokanla, odun yii, ni ogbeni kan toruko re n je David Awopetu mu esun wa si tesan olopaa pe Ogbeni Moses Adegbite to n kawo ponyin rojo yii waa ba oun pe wolii ijo Kerubu ati Serafu to wa ni adugbo Shao loun, ati pe lasiko tawon n se isin pataki kan ni soosi awon, Olorun fi iran han oun pe David nilo lati loo we iwe isegun kan lodo.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 2484 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise

Awon Ebi Oko Mi Maa n Da Soro Wa Ju, O Ti Su Mi — Fatimo
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1533 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Awon Ebi Oko Mi Maa n Da Soro Wa Ju, O Ti Su Mi — Fatimo

Omobinrin kelebe ti ojo ori re ko ti i to meeedogbon ni Fatimo Lawal, sugbon ile oko lo wa ko too keru jade laipe yii, koda o ti bimo okunrin kan foko re naa toruko re n je Rasak Lawal.

Ose to koja ni Fatimo wa si kootu koko-koko to wa l'Agege pelu alaye pe oun fe ki kootu ya oun ya Rasak, ki i toju oun latigba toun ti loyun titi toun fi bimo. Ile awon obi re lawon n gbe, iyen lo se je pe gbogbo oro awon pata ni won maa n da si ni gbogbo igba, oun ko si nifee siru e.

O tun salaye pe Rasak maa n lu oun, oun ko si le gbagbe pe baba oun lo sanwo itoju toun gba ninu oyun ati leyin ibimo, okan oun ko bale nile oko, iyen loun se keru jade toun si gba kootu wa.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1533 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere

Ipo Adele Oba Saki: Awon Afobaje Atawon Odo Yari Mo Ijoba Lowo
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 3868 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Ipo Adele Oba Saki: Awon Afobaje Atawon Odo Yari Mo Ijoba Lowo

Lowolowo bayii, awon afobaje ti won dibo yan Gasali Adegoke lojosi gege bii Bagii, iyen Adele-oba ilu Saki, ti faake kori pe awon ko ni i tele ase ijoba ipinle Oyo lati tun ibo di laaarin ojo merinla.

Lojo Aje, ogbonjo, osu kokanla, odun yii, ni ase waye lati olu-ileese to n ri soro ijoba ibile ati oye jije nipinle Oyo pe kawon afobaje mejeejo to yan Gasali Adegoke gege bii Bagii ilu Saki tun ero won pa nipa siseto idibo tuntun. Eyi waye latari iwe ehonu ti won ri gba latodo idile Kujenya to letoo lati fa omo oye kale, won ni yiyan ti won yan Gasali ko ba ilana oye jije idile naa mu.

Ninu iwe to jade lati sekiteriati ohun lojo Eti, ojo ketadinlogbon, osu kokanla, eyi ti Ogbeni Femi Akano fowo si loruko komisanna ni won ti fi ye idile Kujenya pe pelu awon iwe ehonu tawon ri gba, atundi ibo se pataki. Iwe yii lo mu ki ipade pajawiri waye ni gbongan ile asofin to wa ninu ogba ijoba ibile Iwo-Oorun Saki laarin awon idile ti oro naa kan atawon Afobaje mejeejo, awon agbofinro, awon osise ijoba ibile Iwo-Oorun Saki pelu awon oniroyin.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 3868 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Imo Ofin-Olohun - Awon Ibeere Ati Idahun

Won Ti Yo Oga Olopaa To Lu Iyawo Oniyawo Toyun Fi Jabo Lara e Nise
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 2876 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Ipo Adele Oba Saki: Awon Afobaje Atawon Odo Yari Mo Ijoba Lowo

Ka ni oga olopaa kan ti won pe ni DPO toruko e n je CSP Amos Samuel mo pe inu bibi yoo ko oun si wahala nla ni, o see se ko foju fo o da, sugbon ko mo, o si inu bi titi ti won fi le e ni ofiisi e, ti won si da a pada si olu-ileese olopaa ni Eleweran, nibi ti won ti n se iwadii e bayii.

Ileese olopaa to wa ni Eleweran, niluu Abeokuta ni won ti pase fun oga olopaa naa to je DPO won ni tesan Kemta, Idi Aba, pe ko si loo rokun nile titi tawon yoo fi pari iwadii lori bi won se lo na iyawo oniyawo kan toruko e n je Risikat Abosede Bamidele, toyun osu meji si baje lara e. Komisanna awon olopaa nipinle Ogun, Abdulmajid Ali, lo pase yii leyin ti won lo gbo nipa isele to waye ohun.

Samuel la gbo pe o sinu bi lose to koja lohun-un nigba to lu obinrin naa nilukulu lori esun pe o n pe lori foonu lale tiyen sabewo sodo oko e ti won ti mole. Iwe Iroyin Yoruba gbo pe lakooko ti obinrin naa pe okan lara awon egbon oko e lori foonu lori bi won yoo se gba beeli oko e ni oga olopaa ohun rin sasiko, sugbon kaka ko fi suuru yanju e tabi ba obinrin naa soro, se ni won so pe egun aso olopaa to wo gun un, to si da ibinu bole, bee lo ju igbati ako si iyawo oniyawo yii. Leyin to lu u tan lo tun fa obinrin naa le okan lara awon omoose e lowo, tiyen naa si tun koya fun un ko too di pe won ti i mole.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 2876 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo

Nitori Owo Eja To Sonu, Kunle Gbe Ayoonu Gbigbona Le Omo Iyawo e Leyin N'Ib
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 7149 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Nitori Owo Eja To Sonu, Kunle Gbe Ayoonu Gbigbona Le Omo Iyawo e Leyin N'Ibadan

Ko si eni ti yoo ri omokunrin eni odun mejila kan, Azeez Yusuf, lati ojo Aiku, (Sannde), ojo kejilelogun, osu kokanla, odun yii, ati leyin bii ose meji si asiko naa ti aanu e ko ni i se e pelu bi egbo nla nla se kun gbogbo eyin ati ejika re, ti inira si han loju omo naa gidigidi.

A®pa; to kun gbogbo ara omo yii ki i se ti pe o subu tabi pe o farapa nibi kan, apa ayoonu gbigbona ni, oko iya e to n je Kunle Anisere lo si han an leemo bee nitori pe o so egberun kan naira nu ninu owo eja yiyan to ba iya re kiri lo.

Leyin to ti koko lu u sugbon ti iyen ko te e lorun lo loo ki ayoonu bo ina, to si da a de Azeez leyin nigba ti kinni ohun ti gbona daadaa.

Amumora bii iso inu eku ni Azeez fi oro naa se titi di ojo keta tisele ohun han sita faye, nigba ti okan ninu awon ore e nileewe, iyen 'IDC Primary School', to n lo ni Gbagi, n'Ibadan sakiyesi pe ara re ko ya, to si bi i leere ohun to se e. Bo se jewo fun ore e yii niyen ti loo fi isele naa to oluko won leti, oluko naa ko si fi oro ohun bo to fi royin fun oga-agba ileewe naa.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 7149 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere

Wahala l'Orile Ilugun, Won Ni Ayederu Ni Yusuf To n Pera e Ni Baale
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 3276 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Johnson Akinpelu, Abeokuta

Wahala l'Orile Ilugun, Won Ni Ayederu Ni Yusuf To n Pera e Ni Baale

Bi nnkan se n lo yii, afaimo ki wahala ma be sile niluu Orile Ilugun, nipinle Ogun, pelu bi won se ni okunrin kan toruko e n je Waheed Olatunde Yusuf, ti inagije re n je 'Olumo Record' se n pe ara e ni Baale ilu naa laije pe ilu yan an sipo.

Gege b'Iwe Iroyin Yoruba se gbo, lojo kejilelogun, osu kewaa, odun yii, ni Baale to wa nibe tele, iyen Oloye Raheem Sule Lawal dagbere faye.

Nitori kiluu naa ma baa salai ni olori ni Oba Dokita Adedapo Adewale Tejuoso to je Osile Oke-Ona Egba se yan awon oloye mesan-an kan gege bii igbimo ti yoo maa dari ilu naa titi ti won yoo fi yan Baale tuntun.

Awon eeyan wonyi so pe Osile fowo si i pe kawon maa sakoso Orile Ilugun lo, o si fowo siwee fawon lojo kokanla, osu kokanla, odun yii.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 3276 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Ijamba Isele Aburu Agbako Ati Ifemi Sofo

Ibon Onike Ni Biola Atawon Ore e Fi Deruba Obinrin Ti Won Fipa Ba Lo Po n'I
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1985 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Florence Babasola, Osogbo

Ibon Onike Ni Biola Atawon Ore e Fi Deruba Obinrin Ti Won Fipa Ba Lo Po n'Ileefe

Adajo kootu majisreeti kan niluu Ileefe ti pase pe ki awon omokunrin meta kan loo se faaji odun Keresimesi won logba ewon latari esun pe won fipa ba omo odun metadinlogun lo po.

Awon omokunrin meteeta ti won fesun kan ohun ni Biola Akinwande, omo odun mejidinlogun Ayoola Awodile, eni odun meeedogbon< ati Sodiq Oyedele to pe ara re lomo odun mokandinlogun.

Gege bi agbejoro fun ileese olopaa lori esun yii, Koburu Ronke Badmus, se salaye fun ileejo, o ni ojo kejilelogun, osu kokanla, odun yii, lawon afurasi naa huwa ohun ni nnkan bii aago meji osan.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1985 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Imo Ofin-Olohun - Awon Ibeere Ati Idahun

Nitori Kiko Ara Bibo Iyawo, Igbeyawo Falilat Ati Rafiu Tuka N'Ilorin
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1462 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Nitori Kiko Ara Bibo Iyawo, Igbeyawo Falilat Ati Rafiu Tuka N'Ilorin

Adajo kootu ibile to wa ni Centre Igbooro, niluu Ilorin, ti tu igbeyawo to wa laarin Ogbeni Rafiu Sadiq ati aya re, Falilat Yusuf, ka latari pe Falilat ti so ara bibo di faaji.

Ose to koja ni Falilat wo oko re lo siwaju Adajo Y.K Kayode ti ile-ejo naa, o si ro o lati jowo, ba oun fopin si igbeyawo olomo merin naa. Nigba ti adajo n beere lowo Rafiu pe se o yonda aya re gege bo se wa ninu esin Islam pe oko gbodo yonda iyawo re ki ile-ejo too le fi ofin tu won ka, se ni Rafiu so pe ki ile-ejo dakun gba oun lowo Falilat, nitori to ba le faramo ase oun, oun si nifee re dokan.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1462 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue

Ile-ejo Pase Ki Won Yegi Fun David Fesun Idigunjale L'Ekiti
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1494 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Stephen Ajagbe, Ado-Ekiti

Ile-ejo Pase Ki Won Yegi Fun David Fesun Idigunjale L'Ekiti

Fun esun idigunjale ati bo se jewo pe loooto loun ti kopa ninu orisiirisii idigunjale, ile-ejo giga to wa niluu Ado-Ekiti ti pase ki won loo yegi fun David Olugboyega ti won fesun kan pe o ji owo to le die ni egberun merinla (14, 570).

Lasiko ti okunrin ohun foju bale-ejo, olopaa to soju ijoba, Alaba Adeyemi, salaye pe odaran naa se ese ohun logunjo, osu keta, odun 2013, lopopona Araromi, niluu Ikere-Ekiti. O ni odaran naa gbe awon ohun ija oloro bii ibon ati ada lati loo ja awon araalu kan lole owo won.

Gege bi alaye re, o gba egberun mejo naira lowo enikan toruko re n je Kola Owolabi, o gba egberun marun-un naira lowo Arabinrin Beatrice Olawumi, o si tun gba egberun kan naira le die lowo Idowu Abiodun.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1494 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose

Awon Omo Egbe Okunkun Yinbon Pa Baba Tee N'Ilorin
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1307 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Awon Omo Egbe Okunkun Yinbon Pa Baba Tee N'Ilorin

Se ni awon omo egbe okunkun gbina je niluu Ilorin l'Ojoru, Wesde, ose to koja lohun-un, ti won si seku pa ogbeni kan toruko re n je Taiye Moses Adewoye si opopona Emir's Road.

Akoroyin wa ri i gbo pe se ni awon omo egbe okunkun naa fi Taye ti opo eeyan tun mo si Baba Tee pe okan lara awon omo egbe okunkun igun miiran, ti won si seku pa a.

ASP Ajayi Okasanmi to je alukoro ileese olopaa ipinle Kwara fidi isele yii mule fun akoroyin wa. O salaye pe eeyan merin ni owo awon ti te lori isele yii, pelu alaye pe orun ni awon obayeje yii ti yinbon fun Baba Tee.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1307 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo

Ile N Jeeyan, Awon Eni Nla Ti Re Koja Lo: Awolowo Fi Ogbon Oselu Gbe Akintola Su
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 12950 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Ile N Jeeyan, Awon Eni Nla Ti Re Koja Lo: Awolowo Fi Ogbon Oselu Gbe Akintola Subu, Sugbon Akintola Fi Ete Owo e Sare Dide

Bi won ba n wa eni to mo ogbon ati ete oselu, yoo soro ki won too ri eni to ta Obafemi Awolowo yo nile wa nibi, nitori awon ti won ni ogbon oselu ki i mo ete re, awon ti won ba si ni ete ki i mo ogbon idi re daadaa. Sugbon ni ti Awolowo, oun ni ogbon, o si tun ni ete, o si mo mejeeji bii eni mo iye owo ni. Ni ti Ladoke Akintola, ete oselu lasan loun ni, oun ko ni ogbon re, bo ba si ti lo ete re lorisiirisii ona, Awolowo yoo fi ogbon tire pa a layo, korobata ni Akintola yoo si ba ara re nile, erin ni Awolowo yoo si maa fi i rin. Gbogbo ete ti Ladoke Akintola n lo ni Awolowo ri, sugbon Akintola ko ni ogbon Awolowo, ko si mo ete re, ogbon ati ete yii si ni Awolowo lo papo to fi reyin Akintola nibere ija won. Gbogbo ohun ti Awolowo se pata lori Akintola lo ba ofin mu, bi ko si je pe awon Sardauna ti won da si i, oro naa le ma di ariwo.

Ofin egbe oselu igba naa ni pe egbe ni yoo fa eni to ba fee du ipo nla kan ninu ijoba kale, bo ba si ti je oruko egbe yii lo lo to fi wole, boya o wole sipo gomina ni o, tabi o wole si ipo olori ijoba, tabi ko je asofin, oruko egbe yii ni yoo fi wa nibe, bi ko ba ti je omo egbe naa mo, tabi ti egbe naa ba le e kuro laarin won, o di dandan ko fi ipo naa sile, ki egbe si fi elomiran to ba fe si i. Sugbon isoro wa ki egbe too le eni to wa nipo kuro legbe, nitori oun naa yoo ti ni awon eeyan tire, awon yii yoo si duro ti i, awon ti won fee le e ko si ni i le se bee, nitori bi irin ba kan irin, okan ni yoo te fun okan, sonso meji nikan ni ko le fi oju rinju.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 12950 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo

Akeem Kole Meta N'Ibadan, O Tun Loo Renti Ile Fun Iyawo e Nita
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 4115 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Akeem Kole Meta N'Ibadan, O Tun Loo Renti Ile Fun Iyawo e Nita

Opo awon abiyamo to wa ni kootu lasiko igbejo toko-taya kan ti won n je Akeem Animasahun ati Khadijat Animasahun n'Ibadan ni won n sadura pe ki Olorun ma je komo awon kagbako iru oko bii oko-iyawo yii, eni to ko odidi ile meta, to si loo renti ile fun iyawo e nita, o ni obinrin naa ko le gbe inu ile oun.

Oro Akeem tubo ya awon ero iworan kootu lenu nigba tiyawo ro ile-ejo lati fopin sigbeyawo won ti ko ti i ju odun merin pere lo (pelu omo meji), ki won si pase pe toun lawon omo mejeeji naa, ti okunrin naa si so pe oun faramo on, ati pe oun yonda awon omo to bi foun naa fun un paapaa.

Nigba to n salaye bi oko e se n fiya je e to, ati idi to se fee ko o sile ni kootu Ojaba to wa laduugbo Mapo n'Ibadan, Khadijat to n gbe ni Oju Odo Olomi, laduugbo Academy, n'Ibadan, so pe yato si bi oko oun se maa n lu oun bii igba teeyan ba n lu omo alaigboran, apo kan aabo naira (N300) lo maa n fun oun atawon omo mejeeji gege bii owo ounje fodidi osu kan.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 4115 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Asakasa Ati Sise Eru Awon Oyinbo Nikose

O Do Ju e! Oogun Oloro Yi Omo Lori, Lo Ba Ti Baba e Pa Ni Abeokuta
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1683 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

O Do Ju e! Oogun Oloro Yi Omo Lori, Lo Ba Ti Baba e Pa Ni Abeokuta

Oro di bo o lo o yago fawon oniroyin l'Ojoru, Wesde, ose to koja nigba tawon ebi okunrin kan ti won n pe Baba Basira dide ogun pe won ko gbodo gbe iroyin omokunrin kan to ti baba e subu, tiyen si gbabe ku.

Lojo Isegun, Tusde, niwadii fi ye wa pe omo baba naa ti won so pe oogun oloro yi lori seku pa a lojule keeedogbon, adugbo Akintobi Badejo, Sabo, niluu Abeokuta.

Gege bi Iwe Iroyin Yoruba se gbo, oro ti ko toro lo waye laarin baba atomo tinu fi bi omo yii, abi ka ni oogun oloro lo yi i lori, o si ti baba e subu, niyen ba daku, osibitu ni dokita ti fidi e mule pe o ti ku.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1683 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin

Aafaa Wo Gau N'Ijare, Orebinrin Re Lo Seyun Fun, Niyen Ba Gbabe Ku
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 3773 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Aafaa Wo Gau N'Ijare, Orebinrin Re Lo Seyun Fun, Niyen Ba Gbabe Ku

Ibi toro aafaa kan, Olayinka Olawale Abdulateef, to n gbe niluu Ijare, nijoba ibile Ifedore, nipinle Ondo, yoo ja si ni ko ti i seni to le so pelu esun ti won fi kan ojise Olorun naa pe o seyun osu mefa fun orebinrin re, Oyewumi Agbeluyi, eyi to sokunfa iku aitojo fun un lojo Aiku, Sannde, ose to koja.

Gege bi Abileko Funke Isaac, egbon oloogbe yii to fisele naa to Iwe Iroyin Yoruba leti se salaye, ile loun wa lojo ti enikan toruko re n je Omolola fi pe oun pe koun waa wo aburo oun nileewosan ijoba niluu Akure to ti n gba itoju. O ni gbogbo itoju tawon dokita fun Oyewumi ni ko jo pe o sise lara re, nitori igbe inu rirun lo n pa loore-koore, to si n lonu mole bii eni tifun re ti ja si meji.

Funke ni ariwo ti oloogbe naa n pa ni pe ki awon sekilo fawon dokita ki won ma se fa omi soun lara, bee lo be awon eeyan e to duro ti i pe ki won ba oun pe Aafaa Yinka pe ko waa gbe oun lo siluu Ijare, nitori pe oun lo mo agbo ti yoo lo foun tara oun yoo fi ya.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 3773 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere

Ote Ni Yoo Ba Aye Wwon Oba Yoruba Yii Je
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 2040 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Ote Ni Yoo Ba Aye Wwon Oba Yoruba Yii Je

Won ni awon oba Osun kan n leri pe awon ko ni i lo sibi ti won ti fee fi Ooni joye, ati pe Owa Ilesa lo saaju won. Won ni Owa so pe won fi oun se alaga, Ataoja lo fa owo oun soke, oun si ti di alaga igbimo lobalola ipinle Osun. Ati Ataoja, ati Owa, atawon ti won wa leyin won, won mo pe ina ote lawon n da yii, won mo pe ote tuntun lawon n bere, won mo pe ina naa yoo si jo laipe, won mo pe wahala mi-in lawon tun fee da sile nile Yoruba ati laduugbo tiwon niyen. Won mo daadaa. Ohun to n fa iru eleyii nile Yoruba ko ye eni kan, ati idi ti awon to ye ko gbin igi alaafia siluu se maa je awon gan-an ni won maa n fee fa igi alaafia tu.

Owa so pe oun loun ti n se adele fun Ooni lati ojo yii wa, ti oun si n se adele alaga nigba ti Ooni ko ba ti le wa sipade. Eleyii ki i se nnkan tuntun tabi ohun to lodi sofin. Bo ba je bee ni Owa ti n je alaga yii tele, ki lo waa fa ikanju, ki lo fa ere giragira, ki lo de ti awon oba Osun ko duro ki won gbade ka Ooni lori ko si gba opa ase, ki won waa jo wa nipade, bi won ba fee fi Owa je alaga, ki won si fi i je alaga. 

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 2040 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin

Se Gomina Ti Won Yan Ni Kogi Yii Yoo Maa Jo Sa
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 2426 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Se Gomina Ti Won Yan Ni Kogi Yii Yoo Maa Jo Sa

Oro awon oloselu, keeyan fi senu ko dake ni, tabi ki eeyan saa maa woran won ni. Gomina ti won yan ni Kogi yii, Yahaya Bello, yoo si ma dunnu bayii o, koda yoo maa yo. Awon onilu yoo maa lu ilu, awon onijo yoo si maa jo, won yoo so pe awon ti ni gomina tuntun. Ko si ohun to buru ninu ki eeyan se oriire ko dunnu, ko si si ohun ti ko dara ninu ki eniyan ba alayo yo ayo. 


Sugbon nibo ni inu eeyan yoo ti maa dun pe oun feru gbabukun. Tabi ta ni yoo so pe oun ko mo pe Yahaya Bello feru gbabukun ni, nibi ti ko ti se lo ti fee je. Ohun ti ko da si ni won pin kan an, ise tawon elomiran se lo di ounje fun un. 

Owo olowo leegun n na, aso alaso loga n da bora, ki eeyan sora lati se ami iru adura bee, nitori oba ilu esan. Ki Oluwa ko ma je ka sowo fun omo elomiran je, sugbon eni to ba fee je ise awon mi-in, ise ti oun naa ko se nibe, ki tohun sora o, nitori ifa a maa fa ni lapo ya.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 2426 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)
 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Ole Jegudujere Olosa Ibaje Olosa Gbajue

Baba Atomo Ji Yusuf Gbe l'Ajase-Ipo, Nigba Ti Won Ko Rowo Gba Lowo e Ni Won
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 2122 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Baba Atomo Ji Yusuf Gbe l'Ajase-Ipo, Nigba Ti Won Ko Rowo Gba Lowo e Ni Won Pa a

Ileese olopaa ipinle Kwara ti taari awon afurasi odaran meta kan, Dore Mohammadu, eni odun marundinlaaadorun-un (65) atawon omo re meji, Shehu Mohammadu to je eni ogun odun ati Mohammadu Bello, eni odun marunlelogun ti gbogbo won n se ise daran-daran lo si kootu lori esun pe won ji eeyan gbe, won si tun seku pa onitohun.

Gege bi agbefoba to n soju ijoba ni kootu, iyen Inspekito Isaac Yakub, se so niwaju Adajo T. Osuolale Ajayi, o ni okunrin kan toruko re n je Shehu Madaki to n gbe ni ago awon Fulani, ni Ajase-Ipo, lo mu esun lo si tesan olopaa pe lojo karundinlogbon, osu kesan-an, odun yii, se ni omo oun toruko re n je Yusuf Chede lo si oja Kara to wa ni Ajase-Ipo, ti ko si pada wale mo. Baba naa salaye pe gbogbo akitiyan oun lati pe omo naa lori foonu lo ja si pabo.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 2122 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Adebowale Atawon Egbe e Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1683 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Adebowale Atawon Egbe e Fipa Ba Omo Odun Metala Lo Po

Afi ki ijoba ipinle Eko tete wa nnkan se soro ifipa-ba-ni-lo-po to n fi gbogbo igba waye ko too di pe o buru ju bo se wa yii lo loro to n tenu awon ero iworan kootu majisreeti Yaba jade lose to koja nigba ti won gbo esun ifipa-ba-ni-lo-po ti won fi kan awon omodekunrin meta kan ti ojo-ori won ko ju odun merinla si merindinlogun lo.

Ohun ti a gbo ni pe omobinrin omo odun metala kan ti a foruko bo lasiiri ni awon olujejo naa, iyen Elijah Adebowale, Suleiman Balogun ati Shefiu Adam pelu awon meta kan towo ko ti i te fipa ba lasepo lojo karun-un, osu kewaa, odun yii, nile akoku kan to wa laduugbo Olopade, ni Iju-Ishaga, l'Ekoo.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1683 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

Se Ka Kuku Loo Be Obasanjo Ko Waa Se Asaaju Awa Yoruba?
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 7816 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Se Ka Kuku Loo Be Obasanjo Ko Waa Se Asaaju Awa Yoruba?

Bo ba je irin ti egbon wa, Egbon Segun, (Obasanjo) rin lo si Ileefe lose to koja yii ti okan e wa, to si je lori ododo, a je pe isokan ti a n wa nile Yoruba ti bere naa niyen. Lojo ti Omooba Enitan Ogunwusi, Ooni Ile Yoruba tuntun, wo ilu naa wa, lojo naa ni Egbon Segun ti lo sodo re lati ki i, o mu awon eeyan mi-in dani ti won je agba nile Yoruba yii naa, won si se odomode ti yoo di baba gbogbo wa naa ni maa wole maraba. Ka sa so pe yato si awon agbaagba Ife, Egbon yii lo tun koko ki oba tuntun naa kaabo. Bi ile Yoruba ba dara, ti ko ba si iyapa, ti ohun gbogbo ba si n lo bo se ye ko ri, bi nnkan se gbodo sele lo sele yii. Bi won ba yan Ooni tuntun, eni to ba je asaaju Yoruba nigba naa gbodo ko awon agbaagba ilu lo si Ife lojo ti oba naa yoo koko de, awon ni won yoo loo pade re, ti won yoo si fi i wo sibi to ba dara, awon ni yoo koko maa ri bi gbogbo etutu ilu to ku ba ti n lo.

Idi ti eyi fi gbodo ri bee ni pe Ooni ki i se oba Ileefe nikan, Oba Yoruba ni. Gbogbo itan yoowu ka pa funra wa, gbogbo ona yoowu ka gba, gbogbo ohun yoowu ki oselu so wa da laarin ara wa, Yoruba gba pe Ileefe lawon ti wa, tabi pe Ife ni orirun gbogbo wa. Niwon igba ti Ileefe ko si ti i parun, ti oba si wa nibe to n dade, ti ase Oduduwa gbogbo si wa lowo re, oun naa ni oba gbogbo wa, iyen ti Yoruba ba fe ki nnkan roju, ti a ko si fe ki aye maa fi wa seleya, ki won maa pe wa ni alaimokan ti ko le to ile ara re, awon oniyeye ti won ko ni orirun. Okun kan ko ni i gun titi ko ma ni ibi ti won ti fa a wa, tabi ibi to ti n gun bo, Yoruba ni orirun, Ileefe si ni orirun wa. Bo ti wu ki omo lowo to, bo ti wu ki omo dagba to, baba re ko sa ni i dobale fun un ko ni oun lo bi baba oun, omo re naa ni won yoo maa pe e. Gbogbo eni yoowu to ba ti Ileefe lo, omo Yooba naa ni.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 7816 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Atoka Feyikogbon - Ninu Oye Esin Ati Imo

Ijoba Soja... Ijoba Soja... Ijoba Soja: 'Danfo Gedegbe, Gedegbe Lomo Wa, Da
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 12999 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Olayiwola Alaga

Ijoba Soja... Ijoba Soja... Ijoba Soja: 'Danfo Gedegbe, Gedegbe Lomo Wa, Danfo Gedegbe'

Orin ti won n ko laye ijoba Gowon ree, nigba tawon osise gbowo Adebo, ti won fi ra moto Danfo Oro ijoba, tabi oro orile-ede, bii oro eda kookan naa lo ri o, iyato die lo kan wa nibe ni.

Bi eda kan ba wa laye ti ko si owo lowo re, oto ni iwa ti yoo maa hu, o le maa se yesa yesa kiri. Ki won too pe e ni eekan, yoo ti dahun leemeji, bee ni yoo maa sare sotun-un sare sosi.

Iru won lawon omo ode-oni maa n pe ni oko-onikanopi nile ana, to se pe bi won ba ni inawo pataki lati se, ti won ba n soro owo dida nibe, ko ni i ba won da si i, sugbon ti won ba n wa awon ti won yoo gbele, awon ti won yoo wa igi ati awon ti won yoo ta kanopi nibe, yoo so pe ki won fi kinni ohun da oun ni, gbogbo re loun yoo se. Sugbon bi owo ba wa lowo re, ko ni i se bee, koda ko ma ju janjala bayii lo, agbada nla ni yoo ko si ti yoo si jokoo sori aga feregede, ti yoo maa pase bii oba. Iyen ni pe bi enikan ba wa ti ko ba lowo lowo, iwa oniwa ni yoo maa hu.

Bo se ri fun eeyan naa lo ri fun orile-ede, eyi si ni awon orile-ede to lowo lowo fi maa n gberaga si awon ti won ko ni, ti won fi maa n di alagbara laye. Nigba ti oro owo Adebo sele ni Naijiria lawon eeyan riran wo, awon ti ko mo Naijiria tele, ti won ko mo bi awon omo Naijiria ti n huwa, won waa ri i pe iyato wa nibe, eni kan ju eni kan lo. Idi ni pe awon eeyan gba owo to po daadaa, ko si bi osise kan ti kere to ti ko gba owo to to apo kan, owo nla leleyii nigba naa, nitori ogorun-un pon-un ni won n pe ni apo kan.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 12999 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Aka-re-rin, Irohin Kayeefi Ati Oro-Apara

Oro Buruku Toun Terin: Awon Omo Poli Ojere Mefa Daku Lakooko Ti Won Fee Sedanwo
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 3705 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Oro Buruku Toun Terin: Awon Omo Poli Ojere Mefa Daku Lakooko Ti Won Fee Sedanwo

Beeyan ba ri i bawon omo ile-eko giga Poli ti Moshood Abiola to wa ni Ojere, niluu Abeokuta, se bere si i subu lule, ti won si n daku lojo Eti, Fraide, ose to koja lakooko ti won n sedanwo ise kan ti won pe ni EED 126, ni gbongan '800 seaters', aanu abiyamo yoo seeyan.

Iwe Iroyin Yoruba gbo pe awon akekoo mefa otooto lo daku lojo naa, tawon kan si subu lule, ti won bere si i bi bii oloyun. Ibi ti won duro si lati wonu gbongan ti won ti fee sedanwo ni won ti n subu lule lairotele.

Iyalenu lo je pe obinrin nikan lawon ti won n daku naa. Ohun ti a gbo ni pe wahala ti won n se lati tete wonu gbongan idanwo naa lo fa a nitori pupo ninu won ni ko jeun kuro nile nitori idanwo naa.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 3705 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Isele Agbaiye Musulumi Ati Irohin Esin

Waheed Ni Ismaila N Ba Iyawo Oun Sun, Lo Ba Sa a Pa N'Ilorin
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 2506 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Waheed Ni Ismaila N Ba Iyawo Oun Sun, Lo Ba Sa a Pa N'Ilorin

Gbogbo eeyan to wa ni kootu majisreeti to wa niluu Ilorin l'Ojoru, Wesde, ose to koja lo n beere kelekele lowo ara won iru ife tabi owu jije ti ogbeni eni ogbon odun kan,Waheed Suleiman, ni to bee to fi wo sunsun, to si fi pa eni to ni o n ba oun du obinrin.

Nigba to n safihan re fun ile-ejo, agbenuso ijoba, Inspekito Mojisola Olamokun, fi esun kan afurasi naa pe se lo se iku pa eeyan, eyi to tako abala kan ninu ti iwe ofin to de iwa odaran lorile-ede yii.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 2506 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise

Iyawo Mi Maa n Lu Mama mi, O Tun n Pe Won Lajee — Morufu
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1393 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Iyawo Mi Maa n Lu Mama mi, O Tun n Pe Won Lajee — Morufu

Babalawo ni Ogbeni Morufu Ajah, ise naa lo n se niluu Eko to n gbe. Ose to koja yii ni baale ile naa mu ejo iyawo re, Deborah Ajah, to fe lodun keta seyin wa si kootu ibile to wa ni Igando, nipinle Eko, pe oun fee ko o sile nitori apa oun ko ka a.

Morufu so fun kootu pe Deborah buru pupo, o maa n lu mama oun sere ni, bee lo maa n pe e lajee. O ni oun funra oun ko bo lowo iya latowo obinrin yii, o maa n lu oun naa nigba tapa oun ko ka a.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1393 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Koko Irohin Ati Olori Atoka/Itan/Ibeere

Ipo Adele Oba Saki Di Wahala, Won Ti Gbera Won Lo Sile-ejo
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 3330 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Ipo Adele Oba Saki Di Wahala, Won Ti Gbera Won Lo Sile-ejo

O see se ki erongba tomode tagba ilu Saki, nipinle Oyo, nipa yiyan oba tuntun laipe fori sanpon pelu bawon kan se n so pe yiyan ti won yan Gasali Adegoke gege bii Bagii ilu naa ko tona.

Idi abajo oro yii ni pe awon molebi Kujenya to letoo lati fa omo oye kale ninu eto idibo to waye lojo kejo, osu kewaa, odun ti a wa yii, nibi ti won ti yan Bagii tuntun naa tun ti gba ileejo lo pe yiyan ti won yan Gasali, gege bii Adele Okere tuntun naa ko ba ofin mu. Won ni amuni-muye lo mu iye awon lo lojo tawon n dibo, iyen lo fa a ti won fi yan Adegoke gege bii Bagii ilu naa.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 3330 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Ogbon Ati Oye: Imo-Amolo Imo-Ero Ati Ise

Owo Te Baba Agbalagba Pelu Ori Eeyan N'Iloro-Ekiti
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1343 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Owo Te Baba Agbalagba Pelu Ori Eeyan N'Iloro-Ekiti

Okunrin afurasi eni odun marundinlogorin kan, James Adeniran atawon afurasi meta miin nileese olopaa ti wo lo sile-ejo majisireeti agba to wa niluu Ado-Ekiti lori esun pe won ba ori eeyan lowo won.

Awon afurasi ohun, Tope Omoleye to je eni odun mokandinlogun; Femi Ajayi, omo ogun odun; ati Dada Owoeye toun je eni odun marundinlaaadota ni won fesun kan pe won gbimo- po lati hu oku okunrin kan, Peter Ajayi, niluu Iloro-Ekiti, ti won si ge ori re lo.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1343 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

Ale Lo Maa N Fi Moto Gbe Iyawo Mi Wale Lati Ibi Ise Lalaale — Jimoh
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 2707 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Olawale Ajao, Ibadan

Ale Lo Maa N Fi Moto Gbe Iyawo Mi Wale Lati Ibi Ise Lalaale — Jimoh

Bi ejo ti okunrin birikila kan, Jimoh Alli, ro ni kootu ba se e tele pelu bo se so pe ale lo maa n gbe iyawo oun wale lati ibi ise lalaale, afaimo ni ko ni i je pe ale ohun lobinrin naa yoo ba lo gbeyin, iyen bi ile-ejo ba tu igbeyawo won ka.

Iyawo birikila yii, Titilayo Alli, lo ro kootu ibile Ojaba to wa ni Mapo, n'Ibadan, lati tu igbeyawo olodun mewaa to wa laarin oun ati oko re ka lojo Eti, (Fraide), to koja. O ni okunrin naa ki i se ojuse oko le oun atawon omo re lori, eyi to mu koun ko jade nile e ninu osu kejila, odun to koja. Sugbon oun ti waa ri i bayii pe igbese naa ko fi bee lagbara to, afi ki ile-ejo kuku tu igbeyawo awon ka patapata.

Ninu awijare re, oko iyawo so pe awawi lasan ni iyawo oun n se nitori gbogbo ojuse oko loun n se lori iyawo atawon omo oun ninu ile, ati pe nitori o n yan ale, ti ife okunrin naa si ti ko si i lori lo se pe ejo naa.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 2707 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Aburu Iwa Ese Idi Agbere Ati Iwa Pansaga

'Omo Egbon Mi Loko Mi Fun Loyun, Mi O Fe e Mo'
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1987 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

'Omo Egbon Mi Loko Mi Fun Loyun, Mi O Fe e Mo'

Adajo kootu ibile kan n'Ilesa ti tu igbeyawo ogbon odun to wa laarin Arabinrin Folake to je eni aadota odun atoko re, Kolade, toun je ogota odun ka lori esun tobinrin naa fi kan oko re pe o fun omo egbon oun kan to n je Kemi to n gbe lodo awon loyun.

Nigba to n soro niwaju adajo, Folake salaye pe oko oun je alagbere, sugbon o ti fiwa naa ba ara re je lodo awon ebi oun bayii pelu bo se fun Kemi to je omo odun metadinlogun loyun.

Oyun naa lo ni won gbiyanju lati se, sugbon to ko lati baje leyin tomo naa ti lo opolopo oogun ibile.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1987 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Irukerudo Ati Awon Iwa Janduku Nilu

Nnkan De! Nitori Oro Ti Ko To Nnkan, Gabriel Lu Henry Pa n'Idanre
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1940 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

Nnkan De! Nitori Oro Ti Ko To Nnkan, Gabriel Lu Henry Pa n'Idanre

Pako bii igba ti maalu ba robe lomokunrin eni ogun odun kan, Francis Gabriel, n wo lagoo olopaa to ti n fimu danrin lowo lori esun pe o seku pa okunrin alabaagbe e kan lasiko ti won jo n ja.

Isele naa la gbo pe o waye lose to koja nile ti okunrin afurasi yii pelu oloogbe naa toruko re n je Henry Allison n gbe to wa loju ona kan to lo si Oja Alade, niluu Idanre, nijoba ibile Idanre, nipinle Ondo.

Gege bi ohun ta a gbo nipa isele yii, oro kekere kan lo da wahala sile laarin awon mejeeji ko too di pe esu ba won lowo si i. Gabriel ni won lo loo ba Henry, o si fesun kan an latari bo se da ile sibi ti ko ye ko da a si ninu ogba ile ti won jo n gbe.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1940 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

 

 

Iroyin Oselu Ati Ojelu: Iwa Awon Oloselu

O Tan! Wahala Egbe Afenifere N Po Si Lehin Ti Fasoranti Kowe Fipo Asaaju Sile
(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1712 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

Lati Owo Akoroyin Olootu

O Tan! Wahala Egbe Afenifere N Po Si Lehin Ti Fasoranti Kowe Fipo Asaaju Sile

Wahala sese bere ni lehin ti Asaaju egbe Afenifere, Alagba Reuben Fasoranti, ti kowe fipo e sile gege bii asaaju egbe naa. Lasiko to n soro nipa ohun to mu un gbe igbese ohun, baba eni ogorin odun naa so pe nitori irepo ti ko si ninu egbe naa mo lo je koun fipo ohun sile.

Gege bi o ti jeyo ninu leta ifiposile ti baba yii ko sawon agba egbe lo ti so pe ohun ibanuje lo je foun bi awon omo egbe ko se wa ni irepo, ti won ko si tele ilana ti Oloogbe Obafemi Awolowo la kale lati je ki isokan wa laarin awon omo Oodua. Baba yii so pe ohun ti ko bojumu to ni bi iyapa se wa ninu egbe Afenifere.

(Abala Lati Ka Eyi Siwaju... | 1712 Oode-Ipese Atoka Yii | Nje E Ni Alaiye Lori Eyi? | Iwon: 0)

 
   
   
   
   
   
   
   

  

 
EsinIslam The Muslim World Portal For Islamics, News, Fatwas, Audios, Videos, Muslim News, Quranic Islamic Articles, Radio, Audio Quran, TV Channels, Newspapers Magazines, Halal Custom Search Results For Islam, Shariah, Fatwa Rulings, News Headlines On Middle East, African American Muslims, European Muslims, Africa And Asia In Arabic, English, Yoruba, Hausa, Indonesian Bahasa, Swahili, French, Urdu, Somali, Persian, Turkish, Arab Forums Of National International Islamic Scholars Writers - Schools, Universities, Colleges, Mosques, Muslim Businesses - Arabic English Koran Translations Transliteration Qur'an, Hadith, Sunnah, Fiqh, Prayers, Salat, Fasting Ramadan, Vidoes, Books On EsinIslam.Com And Muxlima.Com

 

  

 
:-: Go Home :-: Go Top :-:
 
 
 
Ojule :|: Koko Mewa :|: Akole Titun :|: Fi Itan/Irohin/Ibeere Sowo :|: Wadi Ni Ede Yoruba :|: Agbo-Oro Yoruba :|: Egbe Yoruba :|: Se Ayewo :|: Ifiseje Tire :|: Idiwon :|: Atoka :|: Apoti Ifi Atoka Pamo :|: Akopo :|: Atokun Alantakun :|: Eda Ipamo :|: Ibeere Ti O Wopo :|: So Nipa Wa F'Aiye :|: Akopo Iwe
 
Notebook :}-{: مذكرة
 
 
 

 Custom Search EsinIslam بحث مخصص

Google Yahoo Bing Excite Ask Yandex
 

 
← Go The Portal Home →
[] Go The Islamic Mobile & Tablet []
Get in Muslim Forums →
 

- About Us    - Explorer   - Writers   -Reciters   - Rulings   - Contact Us

About Us
من نحن
Our Sheikh
من شيخنا
Contact Us
اتصل بنا
Donate to Us
تبرع عندنا
Fatwa Request
الإستفتاء
Brought To You By The Awqaf London - The Society Of Students Of Sheikh Dr. Abu-Abdullah Adelabu
In partnership with - بالمشاركة مع
World's Scholars and Professionals for State Affairs and the Malikis (WOSSAM) Co-Chaired By Sheikh Dr. Abu-Abdullah Adelabu and Minister Ambassador Prof. Ahmad El-Ibraheemi
:: علماء العالم والمحترفون لشؤون الدول والمالكية يشاركان في رئاستها الشيخ الدكتور أبو عبد الله أديلابو والوزير السفيرالأستاذ أحمد الإبراهيمي

We Are EsinIslam Media Of The Awqaf Students Of Sheikh Abu-Abdullah Adelabu

 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 

Director Umm-Abdullah Adelabu Head Office admin@esinislam.com Amir (President) Sheikh Abu-Abdullah Adelabu (Ph D Damas) sheikh@esinislam.com

 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 

© EsinIslam.Com And Muxlima.Com Designed And Produced By Awqaf London Copyright All Rights Reserved. Media contact publicrelations@esinislam.com

No copyright permission required for users whose works, activities and intentions are for purpose of Da'wah, Islamic studies and services to the Muslims. However The Awqaf's Majlis (Council) does review 'Given Permissions' and 'Media Engagements' as necessary

P. O. Box 46044, Maida Vale, London W9 3WN The United Kingdom Tel: +44 (0) 207 266 2207 Fax: +44 (0) 207 266 1289 / 266 3496

Please Pray For Us And For Our Sheikh - May Salawat Allah And Salaam Allah Be Upon Our Beloved Prophet Muhammad s.a.w

 

© EsinIslam.Com - Muxlima.Com from The Awqaf London

 

الله أكبر :: Allah Is Great